•  
  •  
 

Abstract

My research spanning two decades in Ọ̀yọ́ Palace generated series of questions about access to artistic materials in site-locational spaces, archives and private collections. I probe how scholars have navigated and negotiated these terrains, especially artworks created for religious functions. I explore alternatives to resolve field challenges and consider the effects of such hindrances in art historical research. Drawing on the concept of ọ̀gbẹ̀rì, anecdotes and personal scholarly experiences, I interrogate research access and propose approaches based on personal experience on the importance of Yoruba religion, and practice of initiation.

Iṣẹ́ ìwádì mi fún bíi ogún ọdún sẹ́yìn lórí ààfin Ọ̀yọ́ ṣe okùnfà ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìbéèrè tó níí ṣe pẹ̀lú níní àfààní sí èròjà iṣẹ́-ọnà ní ibi-ìkó- ohun- ìṣẹ̀ǹbáyé- sí ati àwọn àkójọ àwọn aládàáni. Mo ṣe ìwádìí bí àwọn onímọ̀ ṣe ń ṣàyẹ̀wò àti àgbéyẹ̀wò pàápàá jùlọ lórí iṣẹ́-ọnà tó wúlò fún iṣẹ́ ẹ̀sìn. Síwájú sí i, mo ṣàwárí àwọn ọ̀nà mìíràn láti yanjú àwọn ìdènà wọ̀nyí, àti ipa tí àwọn ìdènà bẹ́ẹ̀ ń kó nínú ìwádìí ìtàn iṣẹ́-ọnà. Àgbéyẹ̀wò mi dúró lorí ìtumọ̀ ọ̀gbẹ́rì, àti oríṣiríṣi ìtàn àti ìrírí àwọn onímọ̀ nínú iṣẹ́-ọnà. Mo sì dábàá àwọn ọ̀nà míiràn tó dá lórí ìrírí mi, pàtàkì jùlọ lori iṣẹ́pataki ẹ̀sìn Yorùbá, iṣẹ́-ọnà àti ìmọ̀ dídára pọ̀ mọ́ awo.

Share

COinS
 
 

To view the content in your browser, please download Adobe Reader or, alternately,
you may Download the file to your hard drive.

NOTE: The latest versions of Adobe Reader do not support viewing PDF files within Firefox on Mac OS and if you are using a modern (Intel) Mac, there is no official plugin for viewing PDF files within the browser window.